Journal statistics
How to use the archive
When the cursor changes from an arrow to a pointing finger, it indicates a link that you may click on to select that item.
The blue buttons at the top can be selected to return to the overview or to run a search for specific information.
Most volumes have been split into two parts, each with separate articles. When you select a specific number, all of the articles will be listed with details of the author, date of publication, language and the size of the file that will be downloaded if you choose that option. Just click on the yellow "Download" button to transfer a copy of the article to your own computer or device.
- Language Family: Other Benue-Congo
- Topic #1: Semantics
Àṣamọ̀
(Orís̜̣irís̜̣i òs̜̣ùwọ̀n ni àwọn onímọ̀ ń lò láti fi pín ọ̀rọ̀ orúkọ ní èdè Yorùbá tí í ṣe èdè ìhà Gúúsù mọ ìwọ̀ oorun ilẹ Nàìjíríà. Síbẹ̀, àwọn ìsokọ́ra àti ìṣòro kan ń jẹyọ láti inú ìyàtọ̀ tó wà láàárin àwọn òṣùwọ̀n tí a máa ń lò wọ̀nyí tí ó fi jẹ́ okùta ìdìgbòlù àti ìpèníjà ńlá fún iṣẹ́ ìwádìí ì- fa –kókó ìmọ̀ yọ nínú imọ̀ a-so-kókó-ìmọ̀-mọ́ra. Mímú ạ̀won ìyat̀ọ̀ yìí dọ́gba nípasẹ̀ ìlò ìlànà ẹ̀rọ aṣàmúlò ìtumọ̀ ajẹmọ́ sẹmántì́ìkì jẹ́ àlàfo gbòógì kan tó wa nínú isẹ́ ìwádìí ìmọ̀ ẹ̀dá èdè Yorùbá. Isẹ́ yìí ṣe àkọ́jo àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ tó lárìíyànjiyàn nínú Awóbùlúyì (1978, 2013), ó sì lo ìhun Qualia (Qualia Structure) ti inú ìmò a-lo òfin- ìdàró -féyọ ọ̀rọ̀ (Generative Lexicon) – ìlànà tó ní òdiwòn agbájúmọ́ ìfọ́nka ìtumọ̀ nínú àgb́ekalẹ̀ ẹyọ òrọ̀ fún títú ọ̀rọ̀- orúko- ẹlẹ́yọ ọ̀rọ̀ palẹ̀ tí Pustejovsky (1991a) gbé kalẹ̀. Bébà yìí ṣàfihàn pé àwọn wúnrẹ̀n yìí: kíákíá, wéréwéré, àti àwọn ọ̀rọ̀ bíi mo, mi, o, ó, ìre̩, irè̩, wo̩n tí Awóbùlúyì (1978, 2013) pè ní ọ̀rọ̀ orúkọ kò bá ìlànà ìtúpalẹ̀ Qualia yìí mu, pàápàa ́tí a bá fẹ́ kó wọn jọ sínú asùwọ̀n àká ọ̀rọ̀ tí a fi ń rọ ẹ̀rọ à-so- kókó-ìmọ̀- mọ́ra. Iṣẹ́ ìwádìí yìí parí èrò pé ó sàn ká máa lo gírámà tó rọrùn láti fi sàpèjúwe títú àwọn ọ̀rọ̀ Yorùbá palẹ̀, nítorí kó lè rọrùn fún sísàmúlò wọn nínú ìmọ̀ a-so-kókó-ìmọ̀- mọ́ra tí Gẹ̀ẹ́sị̀ ń pè ní ontological annotations.