Journal statistics
How to use the archive
When the cursor changes from an arrow to a pointing finger, it indicates a link that you may click on to select that item.
The blue buttons at the top can be selected to return to the overview or to run a search for specific information.
Most volumes have been split into two parts, each with separate articles. When you select a specific number, all of the articles will be listed with details of the author, date of publication, language and the size of the file that will be downloaded if you choose that option. Just click on the yellow "Download" button to transfer a copy of the article to your own computer or device.
- Language Family: Other Benue-Congo
- Topic #1: Phonology
Afàyo̩
Is̩é̩ ayèwò fínní-fínní yii ṣe iwadii ati akosile awọn abuda acoustic-phonetic ti awọn implosives ati awọn akùnyùn plosives tó jé̩ è̩da fóònù (allophonic) wọn, ni èdè Mpiemo ti a ń sọ ni Central African Republic. Ni Mpiemo, awọn è̩da fóònù (allophonic) plosives máa ń s̩áájú awọn faweli giga-giga ni ipo ibẹrẹ-òpó ati lé̩yin iró aránmú. Is̩é̩ yìí ṣe afihan gbígbéga àti díndínkùn kíkùnyùn ìgbalè̩-ohùn (amplitude) ati fíkúé̩nsì (frequency F0) alésódo àti adínsódo gẹgẹ bi àbùdá fun implosive ati plosive. Síwájú síi, kíkùnyùn ìgbalè̩-ohùn implosives ati plosives kìí sábàá yí padà. Ní ààrin gbólóhùn, láàrin fáwè̩lì méjì àti nínu gbólóhùn aláìs̩àkiyèsí, batani fíkúé̩nsì ló dára láti fi dá awọn implosives ati plosives mo̩, dipo kíkùnyùn ìgbalè̩-ohùn (amplitude). Ní ìbè̩rè̩ ò̩rò̩, àwo̩n ìje̩yo̩ F0 kò̩ò̩kan má ń fi ipa ohùn ati ìwó̩hùn tó wà níwájú hàn.