Journal statistics

The archive of journals contains 771 items in 153 categories. To date, these have been downloaded 1,079,162 times.

How to use the archive

When the cursor changes from an arrow to a pointing finger, it indicates a link that you may click on to select that item.

The blue buttons at the top can be selected to return to the overview or to run a search for specific information.

Most volumes have been split into two parts, each with separate articles. When you select a specific number, all of the articles will be listed with details of the author, date of publication, language and the size of the file that will be downloaded if you choose that option. Just click on the yellow "Download" button to transfer a copy of the article to your own computer or device.

Download details
  • Language Family: Kwa
  • Topic #1: Syntax
  • Topic #2: Morphology
 A Syntactic Analysis of Yoruba Abbreviated Terms on X Platform        A Syntactic Analysis of Yoruba Abbreviated Terms on X Platform

Àṣamọ̀

Iṣẹ́ ìwádìi. Yìí ṣe àgbéyẹ̀wò ìhun síńtáàsì àwọn ìgékúrú ọ̀rọ̀ Yorùbá (AIOY) lórí pẹpẹ ìbánisọ̀rọ̀ ayélujára X. Ìwádìí yìí ṣe àyẹ̀wò àwọn òté ìyídà tí ó ní ṣe pẹ̀lú ìlànà ìṣẹ̀dá wọn. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìgékúrú jẹ́ ọ̀kan lára ìlànà ìṣẹ̀dá ọ̀rọ̀, kìí ṣe ọ̀kan lára ìlànà ìbílẹ̀ ìṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ lédè Yorùbá, inú èdè Gẹ̀ẹ́sì tí a ti sábà máa ń lò ó ni a ti yá a. Tíọ́rì onípele (Ẹ́sí-baà) àti òfin ìgbéfò abẹ́ tíọ́rì awòté-wògàba ní a fi ṣe àtúpalẹ̀ àwọn ìgékúrú yìí. Àwọn tíọ́rì yìí ṣàlàyé bí òfin ìyídà ṣe so ìhun ìpìlẹ̀ mọ́ ìhun òkè. Ìlànà ìgbésẹ̀ ìyídà mẹ́ta ni ìtúpalẹ̀ iṣẹ́ yìí fúnka mọ́, àwọn ni: ìgékúrú, ìfibọ̀, àti ìgbéfò àwọn fọ́nrán ìhun láti ipò kan sí òmíràn. A gba èròjà-àmúkalẹ̀-fáyẹ̀wò lórí pẹpẹ ìbánisọ̀rọ̀ ayélujára X láti oṣù kìíní ọdún 2023 títí dé oṣù kẹjo ọdún 2024 nípasẹ̀ àwọn àkọsílẹ̀ àti àríwísí olùlò. Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta túìtì lórí ọ̀rọ̀ ìṣèlú, eré ìdárayá, ẹ̀sìn, àti ọ̀rọ̀ ajẹmọ́ takọtabo ni a wò, tí a sì fi tíọ́rì onípele àti òfin ìyídà abẹ́ tíọ́rì awòté-wògàba ṣe àgbéyẹ̀wọ̀ àádọ́ta àwọn ìgékúrú ọ̀rọ̀ Yorùbá (AIOY). Iṣẹ́ ìwádìí yìí fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ọ̀nà mẹ́rin ni a lè pín àwọn ìgékúrú ọ̀rọ̀ orí pẹpẹ ìbánisọ̀rọ̀ ayélujára X sí ní ìlànà síńtáàsì, àwọn ni ọ̀rọ̀ ìgékúrú tí a ṣẹ̀dá láti ara gbólóhùn àlàyé, ìyísódì, àkíyèsí alátẹnumọ́ àti ìbéèrè. Ní ìkádìí, a ṣe àkíyèsí pé fífi ojú ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè ajẹmáwùjọ àti ajẹmọ́hun ṣe àgbéyẹ̀wò ìlànà ìbànisọ̀rọ̀ lóri ayélujára le ṣe ìrànwó fún ṣíṣe àfihàn ipa èdè ayélujára lóri ìdàgbàsókè èdèYorùbá.

Data
Created 2026-Jun-27
Changed 2026-Jun-28
Size 354.31 KB
Author This email address is being protected from spambots. You need JavaScript enabled to view it.
MD5 Checksum 270d2117e126ddf86d99760098900c44
Created by Hasiyatu Abubakari
Changed by Hasiyatu Abubakari
Downloads 24
SHA1 Checksum 0ed9d29ccb0eb7129df33961bb1aac9752db2fa5
Cookies user preferences
We use cookies to ensure you to get the best experience on our website. If you decline the use of cookies, this website may not function as expected.
Accept all
Decline all
Analytics
Tools used to analyze the data to measure the effectiveness of a website and to understand how it works.
Google Analytics
Accept
Decline
Unknown
Google Analytics
Accept
Decline
Google Analytics
Accept
Decline
Functional
Tools used to give you more features when navigating on the website, this can include social sharing.
PHP.net
Accept
Decline
Save